1. Sam 11:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn iranṣẹ na si wá si Gibea ti Saulu, nwọn rohìn na li eti awọn enia: gbogbo enia na si gbe ohùn wọn soke, nwọn si sọkun.

1. Sam 11

1. Sam 11:1-10