1. Sam 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ri bẹ̃ pe, nigbati o yi ẹhin rẹ̀ pada lati lọ kuro lọdọ Samueli, Ọlọrun si fun u li ọkàn miran: gbogbo àmi wọnni si ṣẹ li ọjọ na.

1. Sam 10

1. Sam 10:3-11