1. Sam 10:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn ọmọ Beliali wipe, Ọkunrin yi yio ti ṣe gbà wa? Nwọn kẹgàn rẹ̀, nwọn ko si mu ọrẹ wá fun u. On si dakẹ.

1. Sam 10

1. Sam 10:19-27