1. Sam 10:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si sọ ìwa ijọba fun awọn enia na. O si kọ ọ sinu iwe, o si fi i siwaju Oluwa. Samueli si rán gbogbo enia na lọ, olukuluku si ile rẹ̀.

1. Sam 10

1. Sam 10:16-27