1. Sam 10:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina nwọn si tun bere lọdọ Oluwa sibẹ bi ọkunrin na yio wá ibẹ̀. Oluwa si dahùn wipe, Wõ, o pa ara rẹ̀ mọ lãrin ohun-elò.

1. Sam 10

1. Sam 10:14-26