1. Sam 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

SAMUELI si mu igo ororo, o si tu u si i li ori, o si fi ẹnu kò o li ẹnu, o si wipe, Kò ṣepe nitoriti Oluwa ti fi ororo yàn ọ li olori ini rẹ̀?

1. Sam 10

1. Sam 10:1-2