1. Sam 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi on iti ma ṣe bẹ̃ lọdọdun, nigbati Hanna ba goke lọ si ile Oluwa, bẹni Peninna ima bà a ni inu jẹ; nitorina ama sọkun, kò si jẹun.

1. Sam 1

1. Sam 1:1-11