1. Sam 1:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin na Elkana, ati gbogbo awọn ara ile rẹ̀, goke lọ lati rubọ ọdun si Oluwa, ati lati san ileri ifẹ rẹ̀.

1. Sam 1

1. Sam 1:18-25