1. Sam 1:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Ki iranṣẹbinrin rẹ ki o ri ore-ọfẹ loju rẹ. Bẹ̃li obinrin na ba tirẹ̀ lọ, o si jẹun, ko si fà oju ro mọ.

1. Sam 1

1. Sam 1:15-22