1. Pet 5:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti ki ẹnyin ki o kọ oju ija si pẹlu iduroṣinṣin ninu igbagbọ́, ki ẹnyin ki o mọ̀ pe ìya kanna ni awọn ara nyin ti mbẹ ninu aiye njẹ.

1. Pet 5

1. Pet 5:4-14