1. Pet 4:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ jẹ ki awọn ti njìya gẹgẹ bi ifẹ Ọlọrun, fi ọkàn wọn le e lọwọ pẹlu ni rere iṣe, bi ẹnipe fun Ẹlẹda olõtọ.

1. Pet 4

1. Pet 4:16-19