1. Pet 3:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gẹgẹ bi Sara ti gbọ́ ti Abrahamu, ti o npè e li oluwa: ọmọbinrin ẹniti ẹnyin iṣe, bi ẹnyin ba nṣe rere, ti ohunkohun kò si dẹruba nyìn.

1. Pet 3

1. Pet 3:1-13