1. Pet 3:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori oju Oluwa mbẹ lara awọn olododo, etí rẹ̀ si ṣí si ẹbẹ wọn: ṣugbọn oju Oluwa nwo awọn ti nṣe buburu.

1. Pet 3

1. Pet 3:3-21