1. Pet 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin ti a npamọ́ nipa agbara Ọlọrun nipa igbagbọ́ si igbala, ti a mura lati fihàn ni igba ikẹhin.

1. Pet 1

1. Pet 1:3-11