1. Kro 8:34-37 Yorùbá Bibeli (YCE)

34. Ọmọ Jonatani si ni Meribaali; Meribaali si bi Mika.

35. Awọn ọmọ Mika ni Pitoni ati Meleki, ati Tarea, ati Ahasi.

36. Ahasi si bi Jehoadda; ati Jehoadda si bi Alemeti, ati Asmafeti, ati Simri: Simri si bi Mosa;

37. Mosa si bi Binea, Rafa ọmọ rẹ̀, Eleasari ọmọ rẹ̀, Aseli ọmọ rẹ̀:

1. Kro 8