20. Ati Elienai, ati Siltai, ati Elieli,
21. Ati Adaiah, ati Beraiah, ati Ṣimrati ni awọn ọmọ Ṣimhi;
22. Ati Iṣpani, ati Eberi, ati Elieli,
23. Ati Abdoni, ati Sikri, ati Hanani,
24. Ati Hananiah, ati Elamu, ati Antotiah,
25. Ati Ifediah, ati Penueli, ni awọn ọmọ Ṣaṣaki;
26. Ati Samṣerai, ati Sehariah, ati Ataliah,
27. Ati Jaresiah, ati Eliah, ati Sikri, ni awọn ọmọ Jerohamu.