1. Kro 8:19-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Ati Jakimu, ati Sikri, ati Sabdi,

20. Ati Elienai, ati Siltai, ati Elieli,

21. Ati Adaiah, ati Beraiah, ati Ṣimrati ni awọn ọmọ Ṣimhi;

1. Kro 8