11. Huṣimu si bi Ahitubu ati Elpaali fun u.
12. Awọn ọmọ Elpaali, Eberi, ati Miṣamu ati Ṣameri, ẹniti o kọ́ Ono ati Lodi pẹlu ilu wọn:
13. Beria pẹlu, ati Ṣema, ti nwọn iṣe olori awọn baba awọn ara Ajaloni, awọn ti o le awọn ara Gati kuro.
14. Ati Ahio, Ṣaṣaki, Jerimotu,
15. Ati Sebadiah, ati Aradi, ati Aderi,
16. Ati Mikaeli, ati Ispa, ati Joha, ni awọn ọmọ Beria;