1. Kro 6:43-46 Yorùbá Bibeli (YCE)

43. Ọmọ Jahati, ọmọ Gerṣomu, ọmọ Lefi.

44. Awọn arakunrin wọn, awọn ọmọ Merari duro lọwọ osi: Etani ọmọ Kiṣi, ọmọ Abdi, ọmọ Malluku,

45. Ọmọ Haṣabiah, ọmọ Amasiah, ọmọ Hilkiah,

46. Ọmọ Amsi, ọmọ Bani, ọmọ Ṣameri.

1. Kro 6