1. Kro 3:14-24 Yorùbá Bibeli (YCE)

14. Amoni ọmọ rẹ̀, Josiah ọmọ rẹ̀.

15. Ati awọn ọmọ Josiah; akọbi Johanani, ekeji Jehoiakimu, ẹkẹta Sedekiah, ẹkẹrin Ṣallumu.

16. Ati awọn ọmọ Jehoiakimu: Jekoniah ọmọ rẹ̀, Sedekiah ọmọ rẹ̀,

17. Ati awọn ọmọ Jekoniah; Assiri, Salatieli ọmọ rẹ̀.

18. Malkiramu pẹlu, ati Pedaiah, ati Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama ati Nehabiah,

19. Ati awọn ọmọ Pedaiah; Serubbabeli; ati Ṣimei; ati awọn ọmọ Serubbabeli; Meṣullamu, ati Hananiah, ati Ṣelomiti arabinrin wọn:

20. Ati Haṣuba, ati Oheli, ati Berekiah, ati Hasadiah, Juṣab-hesedi, marun.

21. Ati awọn ọmọ Hananiah; Pelatiah, ati Jesaiah: awọn ọmọ Refaiah, awọn ọmọ Arnani, awọn ọmọ Obadiah, awọn ọmọ Ṣekaniah.

22. Ati awọn ọmọ Ṣekaniah; Ṣemaiah; ati awọn ọmọ Ṣemaiah; Hettuṣi, ati Igeali, ati Bariah, ati Neariah, ati Ṣafati, mẹfa.

23. Ati awọn ọmọ Neariah; Elioenai, ati Hesekiah, ati Asrikamu, meta.

24. Ati awọn ọmọ Elioenai ni, Hodaiah, ati Eliaṣibu, ati Pelaiah, ti Akkubu, ati Johanani, ati Dalaiah, ati Anani, meje.

1. Kro 3