13. Ahasi ọmọ rẹ̀, Hesekiah ọmọ rẹ̀, Manasse ọmọ rẹ̀,
14. Amoni ọmọ rẹ̀, Josiah ọmọ rẹ̀.
15. Ati awọn ọmọ Josiah; akọbi Johanani, ekeji Jehoiakimu, ẹkẹta Sedekiah, ẹkẹrin Ṣallumu.
16. Ati awọn ọmọ Jehoiakimu: Jekoniah ọmọ rẹ̀, Sedekiah ọmọ rẹ̀,
17. Ati awọn ọmọ Jekoniah; Assiri, Salatieli ọmọ rẹ̀.
18. Malkiramu pẹlu, ati Pedaiah, ati Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama ati Nehabiah,