1. Kro 29:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn tali emi, ati kili awọn enia mi, ti a fi le ṣe iranlọwọ tinutinu bi iru eyi? nitori ohun gbogbo ọdọ rẹ ni ti wá, ati ninu ohun ọwọ rẹ li awa ti fi fun ọ.

1. Kro 29

1. Kro 29:8-24