1. Kro 23:20-23 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Ninu awọn ọmọ Ussieli: Mika ekini, ati Jesiah ekeji.

21. Awọn ọmọ Merari; Mali ati Muṣi. Awọn ọmọ Mali; Eleasari ati Kiṣi.

22. Eleasari kú, kò si li ọmọkunrin bikòṣe ọmọbinrin: awọn arakunrin wọn awọn ọmọ Kiṣi si fẹ wọn li aiya.

23. Awọn ọmọ Muṣi; Mali, ati Ederi, ati Jeremoti, mẹta.

1. Kro 23