1. Kro 19:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Joabu ri pe a doju ija kọ on, niwaju ati lẹhin, o yàn ninu gbogbo ãyo Israeli, o si tẹ ogun wọn si awọn ara Siria.

1. Kro 19

1. Kro 19:4-15