1. Kro 12:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nibẹ, ni nwọn si wà pẹlu Dafidi ni ijọ mẹta, nwọn njẹ, nwọn si nmu, nitoriti awọn ará wọn ti pèse fun wọn.

1. Kro 12

1. Kro 12:35-40