1. Kro 12:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu ti Sebuluni, iru awọn ti o jade lọ si ogun ti o mọ̀ ogun iwé, pẹlu gbogbo ohun èlo ogun, ẹgbamẹ̃dọgbọn; ti nwọn kì ifi iye-meji tẹgun.

1. Kro 12

1. Kro 12:32-34