35. Ahihamu ọmọ Sakari, ara Harari, Elifali ọmọ Uri,
36. Heferi ara Mekerati, Ahijah ara Peloni,
37. Hesro ara Karmeli, Naari ọmọ Esbai,
38. Joeli arakunrin Natani, Mibhari ọmọ Haggeri,
39. Saleki ara Ammoni, Naharai ara Beroti, ẹniti nru ihamọra Joabu ọmọ Seruiah,
40. Ira ara Itri, Garobu ara Itri,
41. Uriah ara Heti, Sabadi ọmọ Ahalai,
42. Adina ọmọ Ṣisa ara Reubeni, olori awọn ara Reubeni, ati ọgbọ̀n enia pẹlu rẹ̀.
43. Hanani ọmọ Maaka, ati Jehoṣafati ara Mitini,