1. Kro 1:8-10 Yorùbá Bibeli (YCE)

8. Awọn ọmọ Hamu; Kuṣi, ati Misraimu, Puti, ati Kenaani.

9. Ati awọn ọmọ Kuṣi; Ṣeba, ati Hafila, ati Sabta, ati Raama, ati Sabteka. Ati awọn ọmọ Raama; Ṣeba ati Dedani.

10. Kuṣi si bi Nimrodu: on bẹ̀rẹ si di alagbara li aiye.

1. Kro 1