1. Kro 1:52-54 Yorùbá Bibeli (YCE)

52. Aholibama bãlẹ, Ela bãlẹ, Pinoni bãlẹ,

53. Kenasi bãlẹ, Temani bãlẹ, Mibsari bãlẹ,

54. Magdieli bãlẹ, Iramu bãlẹ. Wọnyi ni awọn bãlẹ Edomu.

1. Kro 1