1. Kro 1:21-31 Yorùbá Bibeli (YCE)

21. Ati Hadoramu, ati Usali, ati Dikla,

22. Ati Ebali, ati Abimaeli, ati Ṣeba,

23. Ati Ofiri, ati Hafila, ati Jobabu. Gbogbo wọnyi li awọn ọmọ Joktani.

24. Ṣemu, Arfaksadi, Ṣela,

25. Eberi, Pelegi, Reu,

26. Serugu, Nahori, Tera,

27. Abramu; on na ni Abrahamu,

28. Awọn ọmọ Abrahamu; Isaaki, ati Iṣmaeli.

29. Wọnyi ni iran wọn: akọbi Iṣmaeli, Nebaioti; ati Kedari, ati Adbeeli, ati Mibsamu,

30. Miṣma, ati Duma, Massa, Hadadi, ati Tema,

31. Jeturi, Nafiṣi, ati Kedema. Wọnyi li awọn ọmọ Iṣmaeli.

1. Kro 1