17. Awọn ọmọ Ṣemu; Elamu, ati Assuri, ati Arfaksadi, ati Ludi, ati Aramu, ati Usi, ati Huli, ati Geteri, ati Meṣeki.
18. Arfaksadi si bi Ṣela; Ṣela si bi Eberi.
19. Ati fun Eberi li a bi ọmọkunrin meji: orukọ ọkan ni Pelegi; nitori li ọjọ rẹ̀ li a pin aiye niya: orukọ arakunrin rẹ̀ si ni Joktani.
20. Joktani si bi Almodadi, ati Ṣelefi, ati Hasarmafeti, ati Jera,
21. Ati Hadoramu, ati Usali, ati Dikla,