1. Kor 9:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin kò mọ̀ pe awọn ti nsáre ije, gbogbo nwọn ni nsáre nitõtọ, ṣugbọn ẹnikan ni ngbà ère na? Ẹ sáre bẹ̃, ki ẹnyin ki o le ri gbà.

1. Kor 9

1. Kor 9:19-27