1. Kor 8:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ṢUGBỌN niti awọn nkan ti a fi rubọ si oriṣa, a mọ̀ pe gbogbo wa li o ni ìmọ. Ìmọ a mã fẹ̀, ṣugbọn ifẹ ni gbe-ni-ro.

1. Kor 8

1. Kor 8:1-6