1. Kor 7:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Aya kò li agbara lori ara rẹ̀, bikoṣe ọkọ: bẹ̃ gẹgẹ li ọkọ pẹlu kò si li agbara lori ara rẹ̀, bikoṣe aya.

1. Kor 7

1. Kor 7:1-6