1. Kor 6:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin kò mọ̀ pe ẹ̀ya-ara Kristi li ara nyin iṣe? njẹ emi o ha mu ẹ̀ya-ara Kristi, ki emi ki o si fi ṣe ẹ̀ya-ara àgbere bi? ki a má ri.

1. Kor 6

1. Kor 6:9-18