1. Kor 6:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ohun gbogbo li o yẹ fun mi, ṣugbọn ki iṣe ohun gbogbo li o li ère: ohun gbogbo li o yẹ fun mi, ṣugbọn emi kì yio jẹ ki a fi mi sabẹ agbara ohunkohun.

1. Kor 6

1. Kor 6:5-17