1. Kor 5:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ jẹ ki a ṣe ajọ na, kì iṣe pẹlu iwukara atijọ, bẹ̃ni ki iṣe pẹlu iwukara arankàn ati ìwa buburu; bikoṣe pẹlu aiwukara ododo ati otitọ.

1. Kor 5

1. Kor 5:4-13