1. Kor 4:20-21 Yorùbá Bibeli (YCE) Nitori ijọba Ọlọrun kì iṣe ninu ọ̀rọ, bikoṣe ninu agbara. Kili ẹnyin nfẹ? emi ó ha tọ̀ nyin wá