1. Kor 4:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ani titi fi di wakati yi li ebi npa wa, ti òrungbẹ si ngbẹ wa, ti a si wà ni ìhoho, ti a si nlù wa, ti a kò si ni ibugbé kan;

1. Kor 4

1. Kor 4:4-19