1. Kor 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ kì iṣe ẹniti o ngbìn nkankan, bẹ̃ni kì iṣe ẹniti mbomirin; bikoṣe Ọlọrun ti o nmu ibisi wá.

1. Kor 3

1. Kor 3:1-12