1. Kor 3:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wàra ni mo ti fi bọ́ nyin, kì iṣe onjẹ: nitori ẹ kò iti le gbà a, nisisiyi na ẹ kò iti le gbà a.

1. Kor 3

1. Kor 3:1-4