1. Kor 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iṣẹ ẹnikẹni ba jóna, on a pàdanù: ṣugbọn on tikararẹ̀ li a o gbalà, ṣugbọn bi ẹni nlà iná kọja.

1. Kor 3

1. Kor 3:7-20