1. Kor 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iṣẹ́ olukuluku enia yio hàn. Nitori ọjọ na yio fi i hàn, nitoripe ninu iná li a o fi i hàn; iná na yio si dán iṣẹ olukuluku wò irú eyiti iṣe.

1. Kor 3

1. Kor 3:12-14