1. Kor 2:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa nsọ̀rọ ọgbọ́n larin awọn ti o pé: ṣugbọn kì iṣe ọgbọ́n ti aiye yi, tabi ti awọn olori aiye yi, ti o di asan:

1. Kor 2

1. Kor 2:1-14