1. Kor 16:22-24 Yorùbá Bibeli (YCE)

22. Bi ẹnikẹni kò ba fẹ Jesu Kristi Oluwa, ẹ jẹ ki o di Anatema. Maranata.

23. Õre-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa ki o pẹlu nyin.

24. Ifẹ mi wà pẹlu gbogbo nyin ninu Kristi Jesu. Amin.

1. Kor 16