1. Kor 15:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi li ẹniti o kere jùlọ ninu awọn Aposteli, emi ẹniti kò yẹ ti a ba pè li Aposteli, nitoriti mo ṣe inunibini si ijọ enia Ọlọrun.

1. Kor 15

1. Kor 15:5-10