1. Kor 15:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin eyini o farahan awọn ará ti o jù ẹ̃dẹgbẹta lọ lẹkanna; apakan ti o pọ̀ju ninu wọn wà titi fi di isisiyi, ṣugbọn awọn diẹ ti sùn.

1. Kor 15

1. Kor 15:1-16