1. Kor 15:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori igbati o ti ṣepe nipa enia ni ikú ti wá, nipa enia li ajinde ninu okú si ti wá pẹlu.

1. Kor 15

1. Kor 15:19-29