1. Kor 14:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ si li ẹnyin, bikoṣepe ẹnyin ba nfi ahọ́n nyin sọrọ ti o ye ni, a o ti ṣe mọ̀ ohun ti a nwi? nitoripe ẹnyin o sọ̀rọ si ofurufu.

1. Kor 14

1. Kor 14:3-16