1. Kor 13:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

A mã farada ohun gbogbo, a mã gbà ohun gbogbo gbọ́, a mã reti ohun gbogbo, a mã fàiyarán ohun gbogbo.

1. Kor 13

1. Kor 13:5-13